Diutaronomi 5:27 BIBELI MIMỌ (BM)

Ìwọ Mose, súnmọ́ ọ̀dọ̀ rẹ̀, kí o sì gbọ́ gbogbo ohun tí OLUWA Ọlọrun yóo sọ, kí o wá sọ fún wa, a óo sì ṣe é.’

Diutaronomi 5

Diutaronomi 5:21-33