Diutaronomi 5:26 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí pé ninu gbogbo ẹ̀dá alààyè, ta ni ó tíì gbọ́ ohùn OLUWA Ọlọrun alààyè rí láti inú iná, gẹ́gẹ́ bí àwa ti gbọ́ ọ yìí, tí ó sì wà láàyè?

Diutaronomi 5

Diutaronomi 5:21-33