Diutaronomi 4:22 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí náà, mo níláti kú ní ìhín yìí, n kò gbọdọ̀ rékọjá sí òdìkejì Jọdani, ṣugbọn ẹ̀yin óo rékọjá sí òdìkejì rẹ̀, ẹ óo sì gba ilẹ̀ dáradára náà.

Diutaronomi 4

Diutaronomi 4:15-29