Diutaronomi 4:20 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọlọrun ti yọ yín kúrò ní ilẹ̀ Ijipti, ilẹ̀ tí ó dàbí iná ìléru ńlá, ó ko yín jáde láti jẹ́ eniyan rẹ̀, gẹ́gẹ́ bí ẹ ti jẹ́ lónìí.

Diutaronomi 4

Diutaronomi 4:18-23