Diutaronomi 4:15 BIBELI MIMỌ (BM)

“Nítorí náà, ẹ ṣọ́ra gidigidi, níwọ̀n ìgbà tí ẹ kò rí ìrísí OLUWA ní ọjọ́ tí ó ba yín sọ̀rọ̀ láàrin iná ní Horebu,

Diutaronomi 4

Diutaronomi 4:12-24