Diutaronomi 4:14 BIBELI MIMỌ (BM)

OLUWA pàṣẹ fún mi nígbà náà, láti kọ yín ní ìlànà ati òfin rẹ̀, kí ẹ lè máa tẹ̀lé wọn ní ilẹ̀ tí ẹ̀ ń lọ gbà.

Diutaronomi 4

Diutaronomi 4:4-15