Diutaronomi 30:5 BIBELI MIMỌ (BM)

OLUWA Ọlọrun yín yóo tún da yín pada sí ilẹ̀ àwọn baba yín, ilẹ̀ náà yóo tún pada di tiyín, OLUWA yóo mú kí ó dára fun yín, yóo mú kí ẹ pọ̀ ju àwọn baba yín lọ.

Diutaronomi 30

Diutaronomi 30:1-9