Diutaronomi 30:4 BIBELI MIMỌ (BM)

Ibi yòówù tí OLUWA bá fọn yín ká sí ninu ayé, bí ó tilẹ̀ jẹ́ òpin ayé, OLUWA yóo wa yín rí, yóo sì ko yín jọ.

Diutaronomi 30

Diutaronomi 30:1-5