Diutaronomi 30:18 BIBELI MIMỌ (BM)

mo wí fun yín gbangba lónìí pé, ẹ óo parun. Ẹ kò ní pẹ́ rárá lórí ilẹ̀ tí ẹ̀ ń gòkè Jọdani lọ gbà, tí yóo sì di tiyín.

Diutaronomi 30

Diutaronomi 30:11-20