Diutaronomi 30:17 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn bí ọkàn yín bá yipada, tí ẹ kọ̀, tí ẹ kò gbọ́ tirẹ̀, tí ẹ bá jẹ́ kí wọn fà yín lọ bọ àwọn oriṣa, tí ẹ sì ń sìn wọ́n,

Diutaronomi 30

Diutaronomi 30:11-20