Diutaronomi 28:61 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn àìsàn mìíràn ati ìpọ́njú tí wọn kò kọ sinu ìwé òfin yìí ni OLUWA yóo dà bò yín títí tí ẹ óo fi parun.

Diutaronomi 28

Diutaronomi 28:57-68