Diutaronomi 28:60 BIBELI MIMỌ (BM)

Gbogbo àwọn àrùn burúkú ilẹ̀ Ijipti, tí wọ́n bà yín lẹ́rù, ni OLUWA yóo dà bò yín, tí yóo sì wà lára yín.

Diutaronomi 28

Diutaronomi 28:58-61