Diutaronomi 28:49 BIBELI MIMỌ (BM)

OLUWA yóo gbé orílẹ̀-èdè kan, tí ẹ kò gbọ́ èdè wọn, dìde si yín láti òpin ayé; wọn óo yára bí àṣá.

Diutaronomi 28

Diutaronomi 28:46-51