Diutaronomi 27:13 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn ẹ̀yà Reubẹni, ẹ̀yà Gadi, ti Aṣeri, ti Sebuluni, ti Dani ati ti Nafutali yóo sì dúró lórí òkè Ebali láti búra.

Diutaronomi 27

Diutaronomi 27:8-22