Diutaronomi 27:12 BIBELI MIMỌ (BM)

“Nígbà tí ẹ bá kọjá odò Jọdani sí òdìkejì, àwọn ẹ̀yà Simeoni, ẹ̀yà Lefi, ti Juda, ti Isakari, ti Josẹfu ati ti Bẹnjamini yóo dúró lórí òkè Gerisimu láti súre.

Diutaronomi 27

Diutaronomi 27:6-20