Diutaronomi 23:3 BIBELI MIMỌ (BM)

“Ará Amoni ati Moabu kankan kò gbọdọ̀ bá ìjọ eniyan OLUWA péjọ, arọmọdọmọ wọn títí dé ìran kẹwaa kò gbọdọ̀ bá ìjọ eniyan OLUWA péjọ;

Diutaronomi 23

Diutaronomi 23:2-8