Diutaronomi 23:2 BIBELI MIMỌ (BM)

“Ọmọ àlè kankan kò gbọdọ̀ bá ìjọ eniyan OLUWA péjọ, arọmọdọmọ rẹ̀ títí dé ìran kẹwaa kò gbọdọ̀ bá ìjọ eniyan OLUWA péjọ.

Diutaronomi 23

Diutaronomi 23:1-7