Diutaronomi 22:8 BIBELI MIMỌ (BM)

“Tí ẹ bá kọ́ ilé titun, ẹ níláti ṣe ìgbátí sí òrùlé rẹ̀ yípo, kí ẹ má baà wá di ẹlẹ́bi bí ẹnikẹ́ni bá jábọ́ láti orí òrùlé yín, tí ó sì kú.

Diutaronomi 22

Diutaronomi 22:5-12