Diutaronomi 22:7 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ níláti fi ìyá wọn sílẹ̀ kí ó máa lọ ṣugbọn ẹ lè kó àwọn ọmọ rẹ̀, kí ó lè dára fun yín, kí ẹ sì lè pẹ́ láyé.

Diutaronomi 22

Diutaronomi 22:1-10