Diutaronomi 21:7 BIBELI MIMỌ (BM)

Kí wọ́n wí pé, ‘A kò lọ́wọ́ ninu ikú ọkunrin yìí, bẹ́ẹ̀ ni a kò sì mọ ẹni tí ó pa á.

Diutaronomi 21

Diutaronomi 21:1-8