Diutaronomi 21:6 BIBELI MIMỌ (BM)

Kí gbogbo àwọn àgbààgbà tí wọ́n wà ní ìlú náà wẹ ọwọ́ wọn sórí mààlúù tí wọ́n ti lọ́ lọ́rùn pa yìí.

Diutaronomi 21

Diutaronomi 21:2-12