Diutaronomi 21:2 BIBELI MIMỌ (BM)

kí àwọn àgbààgbà ati àwọn adájọ́ yín jáde wá, kí wọ́n wọn ilẹ̀ láti ibi tí wọ́n pa ẹni náà sí títí dé gbogbo àwọn ìlú tí ó wà ní àyíká ibẹ̀.

Diutaronomi 21

Diutaronomi 21:1-6