Diutaronomi 21:1 BIBELI MIMỌ (BM)

“Bí ẹ bá rí òkú eniyan tí wọ́n pa sinu igbó, lórí ilẹ̀ tí OLUWA Ọlọrun yín fun yín, tí ẹ kò sì mọ ẹni tí ó pa á,

Diutaronomi 21

Diutaronomi 21:1-5