Diutaronomi 19:14 BIBELI MIMỌ (BM)

“Ninu ogún tìrẹ tí ó bá kàn ọ́ ninu ilẹ̀ tí OLUWA Ọlọrun yín fun yín láti gbà, o kò gbọdọ̀ sún ohun tí àwọn baba ńlá rẹ bá fi pààlà ilẹ̀.

Diutaronomi 19

Diutaronomi 19:7-21