Diutaronomi 19:13 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ kò gbọdọ̀ ṣàánú rẹ̀ rárá, ṣugbọn ẹ níláti mú ẹ̀bi ẹ̀jẹ̀ aláìṣẹ̀ kúrò láàrin Israẹli, kí ó lè dára fun yín.

Diutaronomi 19

Diutaronomi 19:10-20