Diutaronomi 18:9 BIBELI MIMỌ (BM)

“Nígbà tí ẹ bá dé ilẹ̀ tí OLUWA Ọlọrun yín fun yín, ẹ kò gbọdọ̀ tẹ̀lé ìwà ìríra tí àwọn orílẹ̀-èdè náà ń hù.

Diutaronomi 18

Diutaronomi 18:7-12