Diutaronomi 18:8 BIBELI MIMỌ (BM)

Bákan náà ni wọn yóo jọ pín oúnjẹ wọn láìka ohun tí àwọn ará ilé rẹ̀ bá fi ranṣẹ sí i gẹ́gẹ́ bí ohun tí ó kàn án ninu ogún baba rẹ̀ tí wọ́n tà.

Diutaronomi 18

Diutaronomi 18:1-15