Diutaronomi 16:21 BIBELI MIMỌ (BM)

“Ẹ kò gbọdọ̀ gbin igikígi bí igi oriṣa Aṣera sí ẹ̀bá pẹpẹ OLUWA Ọlọrun yín, nígbà tí ẹ bá ń kọ́ ọ.

Diutaronomi 16

Diutaronomi 16:12-22