Diutaronomi 16:20 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ̀tọ́ nìkan ṣoṣo ni kí ẹ máa ṣe, kí ẹ lè wà láàyè, kí ẹ sì lè jogún ilẹ̀ tí OLUWA Ọlọrun yín fun yín.

Diutaronomi 16

Diutaronomi 16:13-21