Diutaronomi 16:2 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ níláti máa rú ẹbọ àjọ ìrékọjá sí OLUWA Ọlọrun yín láti inú agbo mààlúù yín, tabi agbo aguntan yín, níbi tí ó bá yàn pé kí ẹ ti máa sin òun.

Diutaronomi 16

Diutaronomi 16:1-10