Diutaronomi 16:1 BIBELI MIMỌ (BM)

“Ẹ máa ranti láti máa ṣe àjọ̀dún àjọ ìrékọjá fún OLUWA Ọlọrun yín ninu oṣù Abibu nítorí ninu oṣù Abibu ni ó kó yín jáde ní ilẹ̀ Ijipti, lálẹ́.

Diutaronomi 16

Diutaronomi 16:1-11