Diutaronomi 15:21 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn bí ó bá ní àbààwọ́n kan, bóyá ó jẹ́ arọ ni, tabi afọ́jú, tabi ó ní àbààwọ́n kankan, ẹ kò gbọdọ̀ fi rúbọ sí OLUWA Ọlọrun yín,

Diutaronomi 15

Diutaronomi 15:19-23