Diutaronomi 15:20 BIBELI MIMỌ (BM)

Níbikíbi tí OLUWA Ọlọrun yín bá yàn, ni ẹ ti gbọdọ̀ máa jẹ wọ́n níwájú rẹ̀, ní ọdọọdún; ẹ̀yin ati gbogbo ilé yín.

Diutaronomi 15

Diutaronomi 15:14-23