Diutaronomi 15:1-2 BIBELI MIMỌ (BM)

1. “Ní ọdún keje-keje ni kí ẹ máa ṣe ìdásílẹ̀.

2. Bí ẹ óo ṣe máa ṣe ìdásílẹ̀ náà nìyí: ẹnikẹ́ni tí aládùúgbò rẹ̀, tíí ṣe arakunrin rẹ̀, bá jẹ ní gbèsè kò ní gba ohun tí aládùúgbò rẹ̀ jẹ ẹ́ mọ́, nítorí pé, a ti kéde ìdásílẹ̀ tíí ṣe ti OLUWA.

Diutaronomi 15