Diutaronomi 13:11 BIBELI MIMỌ (BM)

Gbogbo ọmọ Israẹli yóo gbọ́, ẹ̀rù yóo sì bà wọ́n, ẹnikẹ́ni kò sì ní hu irú ìwà burúkú bẹ́ẹ̀ mọ́ láàrin yín.

Diutaronomi 13

Diutaronomi 13:2-18