Diutaronomi 13:10 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ sọ ọ́ ní òkúta pa nítorí tí ó ti gbìyànjú láti fà yín kúrò lọ́dọ̀ OLUWA Ọlọrun yín, tí ó mu yín jáde kúrò ní oko ẹrú ní ilẹ̀ Ijipti.

Diutaronomi 13

Diutaronomi 13:5-18