Diutaronomi 1:45-46 BIBELI MIMỌ (BM)

45. Nígbà tí ẹ pada dé, ẹ bẹ̀rẹ̀ sí sọkún níwájú OLUWA, ṣugbọn OLUWA kò gbọ́ tiyín, bẹ́ẹ̀ ni kò fetí sí ẹkún yín.

46. “Nítorí náà, gbogbo wa wà ní Kadeṣi fún ìgbà pípẹ́.

Diutaronomi 1