Diutaronomi 1:45 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí ẹ pada dé, ẹ bẹ̀rẹ̀ sí sọkún níwájú OLUWA, ṣugbọn OLUWA kò gbọ́ tiyín, bẹ́ẹ̀ ni kò fetí sí ẹkún yín.

Diutaronomi 1

Diutaronomi 1:42-46