Diutaronomi 1:44 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn ará Amori tí wọn ń gbé agbègbè olókè náà bá jáde sí yín, wọ́n le yín bí oyin tíí lé ni, wọ́n sì pa yín ní ìpakúpa láti Seiri títí dé Horima.

Diutaronomi 1

Diutaronomi 1:42-46