Daniẹli 8:16 BIBELI MIMỌ (BM)

Mo gbóhùn ẹnìkan láàrin bèbè kinni keji odò Ulai tí ó wí pé, “Geburẹli, sọ ìtumọ̀ ìran tí ọkunrin yìí rí fún un.”

Daniẹli 8

Daniẹli 8:13-21