Daniẹli 8:15 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí èmi Daniẹli rí ìran náà, bí mo ti bẹ̀rẹ̀ sí wá ọ̀nà láti mọ ìtumọ̀ rẹ̀, ni ẹnìkan bá yọ níwájú mi tí ó dàbí eniyan.

Daniẹli 8

Daniẹli 8:6-23