Daniẹli 7:3 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn ẹranko ńláńlá mẹrin bá jáde láti inú òkun. Ọ̀kan kò jọ̀kan ni àwọn mẹrẹẹrin.

Daniẹli 7

Daniẹli 7:1-11