Daniẹli 7:2 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó ní, “Bí mo ti sùn ní alẹ́, mo rí i lójúran pé afẹ́fẹ́ tí ń fẹ́ láti igun mẹrẹẹrin ayé ń rú omi òkun ńlá sókè.

Daniẹli 7

Daniẹli 7:1-8