Daniẹli 6:9 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí náà, Dariusi ọba fi ọwọ́ sí òfin náà, ó sì fi òǹtẹ̀ tẹ̀ ẹ́.

Daniẹli 6

Daniẹli 6:5-13