Daniẹli 6:8 BIBELI MIMỌ (BM)

Nisinsinyii, kabiyesi, ẹ fi ọwọ́ sí òfin yìí, kí ó lè fi ìdí múlẹ̀, gẹ́gẹ́ bí òfin Mede ati Pasia tí kò gbọdọ̀ yipada.”

Daniẹli 6

Daniẹli 6:4-11