Daniẹli 5:4 BIBELI MIMỌ (BM)

Bí wọn tí ń mu ọtí, ni wọ́n ń yin ère wúrà, ère fadaka, ère irin, ère igi, ati ère òkúta.

Daniẹli 5

Daniẹli 5:1-9