Daniẹli 5:3 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọ́n bá kó àwọn ife wúrà ati ti fadaka tí wọ́n kó ninu tẹmpili ní Jerusalẹmu jáde, wọ́n sì bẹ̀rẹ̀ sí fi wọ́n mu ọtí.

Daniẹli 5

Daniẹli 5:1-7