Daniẹli 12:6 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọ̀kan ninu wọn bi ẹni tí ó wọ aṣọ funfun, tí ó wà lókè odò pé, “Nígbà wo ni àwọn ìṣẹ̀lẹ̀ tí ń bani lẹ́rù wọnyi yóo dópin?”

Daniẹli 12

Daniẹli 12:2-8