Daniẹli 12:5 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà náà ni mo rí i tí àwọn meji dúró létí bèbè odò kan, ọ̀kan lápá ìhín, ọ̀kan lápá ọ̀hún.

Daniẹli 12

Daniẹli 12:1-7