Daniẹli 11:44 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn ìròyìn kan yóo dé láti ìlà oòrùn ati àríwá tí yóo bà á lẹ́rù, yóo sì fi ibinu jáde lọ kọlu ọpọlọpọ, yóo sì pa wọ́n run.

Daniẹli 11

Daniẹli 11:42-45